Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......
Ao wa itun ifa abere ao gun papo mon irun abe obinrin ao da sinu cream toni orun ao tu bintu kan si fifi para. Esora fun agbere o kema loba iyawo oniyawo sun tori won amagbewa gidi