Skip to main content

OSOLE OWO TUTU...


Ori agutan ibile kan eyin ororo 36 afara oyin lopolopo aojo papo. Taba jotan ao ro sinu sere ao gbe sinu aso funfun aogbe ko.
Ao mafi fo eko mun abi kama fi schnap loo ao mawo aso funfun lasiko tanlo ise yii aosini jade losi ibi to jina won amagbe owo nla wafunwa lati bewa nise.

Comments

Oladeen said…
Pls any repercussions on this job
Unknown said…
What are the latter implications does it involve sacrifices?

Popular posts from this blog

ASINA OWO TAARA

Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......