Skip to main content

Posts

Showing posts from November, 2017

OSOLE OWO TUTU...

Ori agutan ibile kan eyin ororo 36 afara oyin lopolopo aojo papo. Taba jotan ao ro sinu sere ao gbe sinu aso funfun aogbe ko. Ao mafi fo eko mun abi kama fi schnap loo ao mawo aso funfun lasiko tanlo ise yii aosini jade losi ibi to jina won amagbe owo nla wafunwa lati bewa nise.